ADISA.

Hi, so my hands found itself writing a yoruba language love poetry. Enjoy.


Ade ori mi
Oko mi, Ife ori Okan aya mi
Oro o le ropo Ife otito ijinle to mo ni si È
Ife mi Óla mi, òla mi                              
Oko orekelawa,


Wo ni o fe awero o ko, ajinke won tun fi lo e leni o ko o ni adufe lo wun e fe.
Baba so mi ni Ajibewa , aye pe mi l adufe, jejelaye fi Ife won, sangosegun pa eran lo ni igbo, otun ra ileke iyebiye, sugbon adisa mi nikan ni mo lo ju fun.

Kaka kin ba olowo lo, kaka kin ba olode lo, adio mi alasooke te mi lorun.
O je mo pe adufe soro fe, imoran Awon eyan da bi omi leyin rakumi si ero Okan ré si Ajibewa.
Ife wa jinle ife otito lati oorun abe ori ite kabiyesi oba aye ati oorun.
Adisa mi, wole wa sun si egbe Ololufe ré.

leyin iku, Ayafi eleduwa nikan lo le Gba mi lowo e
mo fi gbogbo aye mi si Ike e Ade mi   adio opo.


Comments

TRENDING POSTS

Sexual Abuse.

Side Chick.